Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:33 BMY

33 Ó sì mú wọn ní wákàtí náà lóru, ó wẹ ọgbẹ́ wọn; a ṣi bamitíìsì rẹ̀, àti gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀ lójúkan náà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:33 ni o tọ