Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:15 BMY

15 Àwọn tí ó sin Pọ́ọ̀lù wá sì mú un lọ títí dé Átẹ́nì; nígbà tí wọ́n sì gba àṣẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ wá fún Sílà àti Tímótíù pé, ki wọn ó yára tọ òun wá, wọ́n lọ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:15 ni o tọ