Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:21 BMY

21 Nítorí gbogbo àwọn ará Áténì, àti àwọn àlejò tí ń ṣe àtìpó níbẹ̀ kì í ṣe ohun mìíràn jù kí a máa sọ tàbí ki a máa gbọ́ ohun titun lọ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:21 ni o tọ