Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:23 BMY

23 Nítorí bí mo ti ń kọjá lọ, tí mo wo àwọn ohun tí ẹ̀yin ń sìn, mo sì rí pẹpẹ kan tí a kọ àkọlé yìí ṣí, ‘FÚN ỌLỌ́RUN ÀÌMỌ̀.’ Ǹjẹ́ ẹni tí ẹyin ń sìn ni àìmọ̀ òun náà ni èmi ń ṣọ fún yin.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:23 ni o tọ