12 Nígbà tí Gálíónì sì jẹ báalẹ̀ Ákáyà, àwọn Júù fi ìfìmọ̀ṣọ̀kan dide sí Pọ́ọ̀lù wọn sì mú un wá síwájú ìtẹ́ ìdájọ́.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:12 ni o tọ