Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:17 BMY

17 Gbogbo àwọn Gíríkì sì mú Sósìténì, olórí ṣínágógù, wọ́n sì lù ú níwájú ìtẹ́ ìdájọ́. Gálíónì kò sì bìkítà fún nǹkan wọ̀nyí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:17 ni o tọ