28 Nítorí tí o sọ àsọyé fún àwọn Júù ní gbangba, ó ń fi í hàn nínú ìwé-mímọ́ pé, Jésù ni Kíríṣítí.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:28 ni o tọ