Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:5 BMY

5 Nígbà tí Sílà àti Tímótíù sì tí Makedóníà wá, ọ̀rọ̀ náà ká Pọ́ọ̀lù lára, ó ń fi hàn fún àwọn Júù pé, Jésù ni Kírísítì náà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:5 ni o tọ