Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:8 BMY

8 Kírísípù, olórí ṣínágọ́gù, sì gba Olúwa gbọ́ pẹ̀lú gbogbo ilé rẹ̀: àti ọ̀pọ̀ nínú àwọn ara Kọ́ríńtì, nígbà tí wọ́n gbọ́, wọ́n gbàgbọ́, a sì bamitíìsì wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:8 ni o tọ