Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:19 BMY

19 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú àwọn tí ń se alálùpàyídà ni ó kó ìwé wọn jọ, wọ́n dáná sun wọ́n lójú gbogbo ènìyàn: wọ́n sì sirò iye wọn, wọ́n sì rí i, ó jẹ́ ẹgbàámẹ́ẹ̀dọ́gbọ́n ìwọ̀n fàdákà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:19 ni o tọ