8 Nígbà tí ó sì wọ inú Sínágọ́gù lọ ó fi ìgboyà sọ̀rọ̀ ni oṣù mẹ́ta, ó ń fi ọ̀rọ̀ wé ọ̀rọ̀, ó sì ń yí wọn lọ́kàn padà sí nǹkan tí i ṣe tí ìjọba Ọlọ́run.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:8 ni o tọ