Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:17 BMY

17 “ ‘Ní ìkẹyìn ọjọ́, Ọlọ́run wí pé,Èmi yóò tú Ẹ̀mí mí jáde sára ènìyàn gbogbo,àwọn ọmọ yín ọkùnrin àti àwọn ọmọ yín obìnrin yóò máa sọtẹ́lẹ̀àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin yín yóò sì máa ríran,àwọn arúgbó yín yóò sì máa lá àlá;

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:17 ni o tọ