Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:30 BMY

30 Ṣùgbọ́n ó jẹ́ wòlíì, àti bí ó mọ́ pé, Ọlọ́run ti ṣe ìlérí fún òun nínú ìbúra pé nínú irú-ọmọ inú rẹ̀, òun yóò mú ọ̀kan jókòó lórí ìtẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:30 ni o tọ