Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:46 BMY

46 Wọ́n fi ọkàn kan dúró lójoojúmọ́ nínú tẹ́mpílì. Wọ́n ń bu àkàrà ní ilé wọn, wọn ń fi inú dídùn àti ọkàn òtítọ́ jẹ oúnjẹ wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:46 ni o tọ