6 Nígbà tí wọn sì gbọ́ ìró yìí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn péjọ nínú ìdàmú, nítorí tí olúkúlùkù gbọ́ tí wọ́n ń sọ̀rọ̀ ní èdè rẹ̀.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:6 ni o tọ