15 Nígbà tí a sì ṣíkọ̀ kúrò níbẹ̀, ní ijọ́ kejì a dé ọ̀kánkán Kíósì; ní ijọ́ kejì rẹ̀ a dé Sámósì, a sì dúró ní Tírógílíónì: ni ijọ́ kéjì rẹ̀ a sì dé Mílétù.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:15 ni o tọ