Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:2 BMY

2 Nígbà tí ó sì tí la apá ìhà wọ̀nyí kọjá, tí ó sì ti fi ọ̀rọ̀ pupọ gbà wọ́n ní ìyànjú, ó wá sí ilẹ̀ Gíríkì.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:2 ni o tọ