21 Tí mo ń sọ fún àwọn Júù, àti fún àwọn Gíríkì pẹ̀lú, ní ti ìrònúpìwàdà sí Ọlọ́run, àti ti ìgbàgbọ́ nínú Jésù Kírísítì Olúwa wa.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:21 ni o tọ