Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:13 BMY

13 Nígbà náà ni Pọ́ọ̀lù dàhun wí pé, “Èwo ni ẹ̀yin ń ṣe yìí, tí ẹ̀yin ń sọkún, tí ẹ sì ń mú àárẹ̀ bá ọkàn mi; nítorí èmí tí múra tan, kì í se fún dídè nìkan, ṣùgbọ́n láti kú pẹ̀lú ni Jerúsálémù, nítorí orúkọ Jésù Olúwa.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:13 ni o tọ