Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:16 BMY

16 Nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn láti Kéṣáríà bá wa lọ, wọ́n sì mú wa lọ sí ilé Múnásónì ọmọ-ẹ̀yìn àtijọ́ kan ara Sàìpúrọ́sì, lọ́dọ̀ ẹni tí àwa óò dé sí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:16 ni o tọ