Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:30 BMY

30 Gbogbo ìlú sì wà ní ìrúkèrúdo, àwọn ènìyàn sì súré jọ: wọ́n sì mú Pọ́ọ̀lù, wọ́n sì wọ́ ọ jáde kúrò nínú tẹ́ḿpílì: lójúkan náà, a sì ti ìlẹ̀kùn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:30 ni o tọ