Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:7 BMY

7 Nígbà tí a sì ti parí àjò wa láti Tírè, àwa dé Pítólémáì; nígbà ti a sì kí àwọn ará, a sì bá wọn gbé ní ijọ́ kan.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:7 ni o tọ