14 “Nígbà náà ni ó wí pé: ‘Ọlọ́run àwọn baba wa ti yàn ọ́ láti mọ ìfẹ́ rẹ̀, àti láti ri Ẹni Òdodo náà, àti láti gbọ́ ọ̀rọ̀ láti ẹnu rẹ̀.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:14 ni o tọ