4 Mo sì ṣe inúnibíni sí àwọn ènìyàn tí ń tọ ọ̀nà yìí dé ojú ikú wọn, mo dè tọkùnrin àtobìnrin wọ́n, mo sì fi wọ́n sínú túbú,
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:4 ni o tọ