Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:11 BMY

11 Ǹjẹ́ bí mo bá ṣẹ̀, tí mo sí ṣe ohun kan tí ó yẹ fún ikú, èmi kò kọ̀ láti kú: ṣùgbọn bí kò bá sí otítọ́ kan nínú ẹ̀sùn tí àwọn Júù yìí fi mi sùn sí, ẹnìkan kò lẹ́tọ̀ọ́ láti fà mí lé wọn lọ́wọ́. Mo fí ọ̀ràn mi lọ Késárì.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:11 ni o tọ