Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:14 BMY

14 Bí wọ́n sì tí wà níbẹ̀ lọ́jọ́ púpọ̀, Fẹ́sítúsì mú ọ̀ràn Pọ́ọ̀lù wá síwájú ọba, wí pé, “Fẹ́líkísì fi ọkùnrin kan ṣílẹ̀ nínú túbú.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:14 ni o tọ