Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:10 BMY

10 Èyi ni mo sì ṣe ni Jerúsálémù. Pẹ̀lú àṣẹ tí mo tí gba lọ́dọ̀ àwọn olórí àlùfáà, mo sọ àwọn púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn mímọ́ sí inú túbú, nígbà tí wọ́n sí ń pa wọ́n, mo ní ohùn sí i.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:10 ni o tọ