Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:14 BMY

14 Gbogbo wa sì ṣubú lulẹ̀, mo gbọ́ ohùn tí ń fọ sì mi ni èdè Hébérù pé, ‘Ṣọ́ọ̀lù, Ṣọ́ọ̀lù! Èéṣe tí ìwọ fi ń ṣe inúnibíni ṣí mi? Ohun ìrora ní fún ọ láti tàpá sí ẹ̀gún!’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:14 ni o tọ