Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:31 BMY

31 Nígbà tí wọn wọ yẹ̀wù lọ, wọn bá ara wọn jíròrò, wọ́n sọ pé, “Ọkùnrin yìí kò ṣe nǹkan kan tí ó yẹ sí ikú tàbí sì ẹ̀wọ̀n.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:31 ni o tọ