Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:3 BMY

3 Ní ijọ́ kejì, a gúnlẹ̀ sí Sídónì. Júlíọ́sì sì ṣe inú rere sì Pọ́ọ̀lù, ó sì fún un láàyè kí ó máa tọ àwọn ọrẹ̀ rẹ̀ lọ kí wọn le se ìtọ́jú rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:3 ni o tọ