Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:43 BMY

43 Ṣùgbọ́n balógun ọ̀rún ń fẹ́ gba Pọ́ọ̀lù là, ó kọ èrò wọn, ó sì pàṣẹ fún àwọn tí ó lè wẹ̀ kí wọn bọ́ sí òkun lọ sì ilẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:43 ni o tọ