Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:13 BMY

13 Láti ibẹ̀ nígbà tí a lọ yíká; a dé Régíónì: nígbà tí ó sì di ọjọ́ kejì, afẹ́fẹ́ gúsù bẹ̀rẹ̀ sí ní fẹ́, ní ọjọ́ kejì rẹ̀ a sì dé Pútéólì.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:13 ni o tọ