16 Nígbà tí a sì dé Róòmù, olórí àwọn ọmọ ogun fi àwọn òǹdè lé olórí ẹ̀sọ́ lọ́wọ́: ṣùgbọ́n wọ́n gba Pọ́ọ̀lù láàyè láti máa dágbé fún ara rẹ̀ pẹ̀lú ọmọ-ogun tí ó ń sọ́ ọ.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:16 ni o tọ