Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:6 BMY

6 Ṣùgbọ́n wọn ń wòye ìgbà tí yóò wù, tàbí tí yóò sì ṣúbu lulẹ̀ kú lójijì: nígbà tí wọ́n wò títí, tí wọn kò sì rí nǹkan kan kí ó ṣe é, wọ́n pa èrò wọn dà pé, òrìṣà kan ni ọkùnrin yìí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:6 ni o tọ