Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:9 BMY

9 Nígbà tí èyí sì ṣe tán, àwọn ìyókù tí ó ni àrùn ni erékùṣù náà tọ̀ ọ́ wá, ó sì mú wọn láradá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:9 ni o tọ