Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:14 BMY

14 Ṣùgbọ́n ẹ̀yin sẹ́ Ẹni-Mímọ́ àti Olóòtọ̀ náà, ẹ̀yin sì béèrè kí a fi apànìyàn fún un yín.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:14 ni o tọ