Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:26 BMY

26 Nígbà ti Ọlọ́run jí Jésù Ọmọ rẹ̀ dìde, ó kọ́ rán an sí i yín láti bùkún fún un yín, nípa yíyí olúkúlùkù yín padà kúrò nínú ìwà búburú rẹ̀.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:26 ni o tọ