Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:38 BMY

38 Ǹjẹ́ èmi wí fún un yín nísinsin yìí, Ẹ gáfárà fún àwọn ọkùnrin wọ̀nyí, kí ẹ sí fi wọn sílẹ̀, nítorí bí ìmọ̀ tàbí iṣẹ́ yìí bá jẹ́ ti ènìyàn, a ó bì í ṣúbu.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:38 ni o tọ