Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:3 BMY

3 Nítorí náà, ará, ẹ wo ọkùnrin méje nínú yín, olórúkọ rere, tí ó kún fún Ẹ̀mí-Mímọ́ àti fún ọgbọ́n, tí àwa lè yàn sí iṣẹ́ yìí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:3 ni o tọ