Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:15 BMY

15 Nígbà náà ni Jákọ́bù sọ̀kalẹ̀ lọ sí Íjíbítì, ní ibi tí òun àti àwọn baba wa kú sí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:15 ni o tọ