32 Wí pé ‘Èmi ni Ọlọ́run àwọn baba rẹ, Ọlọ́run Ábúráhámù àti Ọlọ́run Ísáákì, àti Ọlọ́run Jákọ́bù,’ Mósè sì wárìrì pẹ̀lú ìbẹ̀rù, kò sì dàṣà láti wò ó mọ́.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:32 ni o tọ