35 “Mósè náà yìí tí wọ́n kọ̀, wí pé, ‘Ta ni ó fi jẹ olórí àti onídàájọ́?’ Òun náà ni Ọlọ́run rán lọ láti ọwọ́ ańgẹ́lì, tí ó farahàn án ní ìgbẹ́, láti ṣe olórí àti olùdáǹdè.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:35 ni o tọ