56 Ó sì wí pé, “Wò ó, mo rí ọ̀run ṣí sílẹ̀, Ọmọ Ènìyàn sì dúró ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run.”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:56 ni o tọ