60 Nígbà náà ni ó wólẹ̀ lórí eékún rẹ̀, ó kígbe sókè pé, “Olúwa, má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ yìí sí wọn ní ọrùn.” Nígbà ti ó sì wí èyí tán, ó sùn lọ.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:60 ni o tọ