13 Símónì tikararẹ̀ sì gbàgbọ́ pẹ̀lú nígbà ti a sì bámitíìsì rẹ̀, ó sì tẹ̀ṣíwájú pẹ̀lú Fílípì, ó wo iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ agbára tí ń ti ọwọ́ Fílípì ṣe, ẹnu sì yà á.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:13 ni o tọ