Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:18 BMY

18 Nígbà tí Símónì rí i pé nípa gbígbe ọwọ́ leni ni a ń ti ọwọ́ àwọn àpósítélì fi Ẹ̀mí Mímọ́ fún ni, ó fi owó lọ̀ wọ́n,

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:18 ni o tọ