Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:21 BMY

21 Ìwọ kò ni ipa tàbí ìpín nínú ọ̀ràn yìí, nítorí ọkàn rẹ kò ṣe déedé níwájú Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:21 ni o tọ