Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:24 BMY

24 Nígbà náà ni Símónì dáhùn, ó sì wí pé, “Ẹ gbàdúrà sọ́dọ̀ Olúwa fún mi, kí ọ̀kan nínú ohun tí ẹ̀yin tí sọ má ṣe bá mi.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:24 ni o tọ