Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:37 BMY

37 Fílípì sì wí pé, “Bí ìwọ bá gbàgbọ́ tọkàntọkàn, a lè bamitíìsì rẹ.” Ìwẹ̀fà náà sì dáhùn pé, “Mo gbàgbọ́ pé Jésù Kírísítì Ọmọ Ọlọ́run ni.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:37 ni o tọ