Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:7 BMY

7 Nítorí tí àwọn ẹ̀mí àìmọ́ ń kígbe sókè bí wọ́n ti ń jáde kúrò lára àwọn ènìyàn, ọ̀pọ̀ àwọn arọ àti amúkùn-ún ni ó sì gba ìmúláradá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:7 ni o tọ